Ilé Èdè Yorùbá
  • Ilé Èdè Yorùbá
  • Sabor da Cultura
  • Livro/Compre o Livro
  • Alfabeto/Leitura
  • Curso do Ioruba
  • Eventos
  • Fale Conosco
Curso do Ioruba

Baixe o programa e começe a escrever em Ioruba ou qualquer outra língua do mundo. Pode testar e comprar depois.


Saboreando a Cultura em Yorùbá

Local:             Casa de Cultura Mário Quintana
                      Rua dos Andradas, 736
                      Centro  Porto Alegre - RS, 90020-004 - Sala C2.

Data:              Sábado, dia 23 e junho de 2012

Horário:          18 horas


Atenção: Aberto para o público. Compareçam!!!

Objetivo:         Momento de confraternização onde haverá uma seção de autógrafos da obra: Uma Abordagem Moderna ao Yorùbá (Nagô). Um momento de cultura com a introdução à filosofia Iorubana, POR MEIO  DE PROVÉRBIOS  e reflexões SOBRE A cultura Yorùbá, finalizando com UMA singela comemoração entre os participantes.

Sétimo Dia de Curso de Fruição do Yorùbá - 19/06/2012.

História de Títílayọ̀. Ela é uma jovem de EUA que estudou língua e cultura Ioruba na Universidade de Wisconsin durante tres anos e depoi foi à Nigéria e hoje fala e entende bem a língua. clique aqui ou pode copiar e colar no seu navegador este endereço:  http://www.youtube.com/watch?v=cdP_UNoz4Mg
O grande desafio é, já que ela sabe falar ioruba, você também pode. Então, vamos lá minha gente!

          
Quarto Dia de Curso de Fruição do Yorùbá - 12/06/2012.

Aqui está o texto e arquivo de da música (clique aqui ou navegue ao final de texto para ouvir a música)

COMFORT OMOGE - Ọlọrun Mi Ìwọ Ni ma sìn

Egudu egudu
Egudu lo n jẹ
Agbe ọmọ ‘kalẹ o
O

Àdákọ:        Ọlorun mi, Iwọ ni ma sin titi aye mi Amin o. 2x
L’ọjọ mo ri jẹ, Oluwa lat’ọdọ Rẹ wa,
L’ọjọ mo ri mu, Oluwa a lat’ọdọ Rẹ bọ o.
Ọlorun mi Iwọ ni ma sin titi aye mi Amin o.

E Oluwa

Àjọkọ:         Ọlorun mi,
                  Iwọ ni ma sin titi aye mi Amin o.
Àdákọ:        Ọlorun mi,
Àjọkọ:         Iwọ ni ma sin titi aye mi Amin o.
Àdákọ:        L’ọjọ mo ri jẹ,
Ègbè:          lat’ọdọ Rẹ wa,
Àdákọ:        L’ọjọ mo ri mu,
Ègbè:          lat’ọdọ Rẹ wa.
Àjọkọ:         Ọlorun mi Iwọ ni ma sin titi aye o Amin o.
Àdákọ:        E e, Ọlorun mi Iwọ ni mọ sin titi aye mi Amin o.
                  Ọlorun mi Iwọ ni mọ sin titi aye (ìlù) mi Amin o.                           Oluwa,
                  L’ọjọ mo ri jẹ, lat’ọdọ Rẹ wa,
                  Lọjọ mo ri mu, lat’ọdọ Rẹ bọ o.
                  Ọlorun mi Iwọ ni ma sin titi aye mi Amin kẹ o.
                  Oluwa

Àjọkọ:         Ọlorun mi, Iwọ ni ma sin titi aye o Amin o.
Àdákọ:        Ọlorun mi,
Àjọkọ:         Iwọ ni ma sin titi aye o Amin o.
Àdákọ:        E, l’ọjọ mo ri jẹ,
Àjọkọ:         lat’ọdọ Rẹ wa,
Àdákọ:        L’ọjọ mo ri mu, Oluwa
Àjọkọ:         lat’ọdọ Rẹ wa.
                  Ọlorun mi Iwọ ni ma sin titi aye o Amin o.

Àdákọ:        E, Ọlorun mi Iwọ ni ma sin titi aye mi Amin o.
                  Ọlorun mi Iwọ ni ma sin titi aye mi Amin o. Oluwa
                  L’ọjọ mo ri jẹ, Ọlọrun Ọba lat’ọdọ Rẹ wa,
                  Lọjọ mo ri mu, Oluwa temi lat’ọdọ Rẹ bọ.
                  Ọlorun mi Iwọ ni ma sin titi aye mi Amin o. Oluwa

Àjọkọ:         Ọlorun mi Iwọ ni ma sin titi aye o Amin o.

Àdákọ:        Ọlorun mi
Ègbè:          Iwọ ni ma sin titi aye o Amin o.
Àdákọ:        E l’ọjọ mo ri jẹ,
Ègbè:          Oluwa lat’ọdọ Rẹ wa,
Àdákọ:        L’ọjọ mo ri mu,
Ègbè:          e o lat’ọdọ Rẹ bọ
Àjọkọ:         Ọlorun mi Iwọ ni ma sin titi aye mi Amin o.

Àdákọ:        Ọpẹ o Baba ọpẹ lo ma yẹ fun Ẹ ran o
Ègbè:          Ọpẹ o Baba ọpẹ lo yẹ fun Ọ
Àdákọ:        Ọpẹ l’o yẹ fun Ẹ Ọlọrun Ọba ọpẹ l’o ma yẹ fun Ẹ
Ègbè:          Ọpẹ o Baba ọpẹ lo yẹ fun Ọ
Àdákọ:        Ọmọde ba dupẹ ore ana o a ri bukun t’eni gba o
Ègbè:          Ọpẹ o Baba ọpẹ lo ma yẹ fun Ẹ
Àdákọ:        Ọpẹ l’o yẹ fun Ẹ Ọlọrun ọba ọpẹ lo ma yẹ fun Ẹ ran o
Ègbè:          Ọpẹ o Baba ọpẹ lo ma yẹ fun Ọ
Àdákọ:        Ọmọde ba dupẹ ore ana o a ri ’bukun t’eni gba o                           Ọlọrun Ọba
Ègbè:          Ọpẹ o Baba ọpẹ lo ma yẹ fun Ọ
Àdákọ:        Ugboyi wo da mi Ọlọrun mo ma mu gba Ẹ o
Ègbè:          Ọpẹ o Baba ọpẹ lo ma yẹ fun Ọ.
Àdákọ:        Ọpẹ l’o yẹ fun Ẹ o Ọlọrun ọba ọpẹ yẹ fun Ẹ ran o
Ègbè:          Ọpẹ o Baba ọpẹ lo ma yẹ fun Ọ
Àdákọ:        Ọba Atẹrẹrẹ kari aye o Oluwa mo ma dupẹ o o
Ègbè:          Ọpẹ o Baba ọpẹ lo ma yẹ fun Ẹ
Àdákọ:        Ọba aragbaye t’igbo kiji mo ma dupẹ Ọlọrun Ọba
Ègbè:          Ọpẹ o Baba ọpẹ lo ma yẹ fun Ẹ
Àdákọ:        Ugboyi wo da mi Ọlọrun mo ma mu gba ẹ ba Ẹ ṣa o
Ègbè:          Ọpẹ o Baba ọpẹ lo ma yẹ fun Ọ
Àdákọ:        Ọpẹ o Baba ọpẹ lo ma yẹ fun Ẹ
Ègbè:          Ọpẹ o Baba ọpẹ lo ma yẹ fun Ẹ



http://www.youtube.com/watch?v=QxQsf9faHa8
 

Terceiro Dia de Curso de Fruição do Yorùbá - 09/06/2012.

Segundo Dia de Curso de Fruição do Yorùbá - 08/06/2012.

Aula Inaugural de Curso de Fruição do Yorùbá - 05/06/2012.


Web Hosting by iPage